Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 24:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n tún ilé OLUWA náà ṣe tán, wọ́n kó owó tí ó kù pada sọ́dọ̀ ọba ati Jehoiada. Wọ́n fi owó náà ṣe àwọn ohun èlò fún ìsìn ati ẹbọ sísun ní ilé OLUWA, ati àwo fún turari ati ohun èlò wúrà ati fadaka.Wọ́n sì ń rú ẹbọ sísun ní ilé OLUWA lojoojumọ, ní gbogbo àkókò Jehoiada.

Ka pipe ipin Kronika Keji 24

Wo Kronika Keji 24:14 ni o tọ