Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ ọdún meje ni Joaṣi nígbà tí ó gorí oyè, ó sì jọba ní Jerusalẹmu fún ogoji ọdún. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Sibaya, ará Beeriṣeba.

Ka pipe ipin Kronika Keji 24

Wo Kronika Keji 24:1 ni o tọ