Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 23:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn pàdé ninu ilé Ọlọrun, wọ́n sì bá ọba dá majẹmu níbẹ̀. Jehoiada wí fún wọn pé, “Ẹ wò ó! Ọmọ ọba nìyí, ó tó àkókò láti fi jọba nisinsinyii, gẹ́gẹ́ bí ìlérí tí OLUWA ṣe pé ìran Dafidi ni yóo máa jọba.

Ka pipe ipin Kronika Keji 23

Wo Kronika Keji 23:3 ni o tọ