Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 23:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, gbogbo wọn lọ sí ilé oriṣa Baali, wọ́n wó o palẹ̀, wọ́n wó pẹpẹ ati àwọn ère túútúú, wọ́n sì pa Matani, tí ó jẹ́ alufaa Baali, níwájú pẹpẹ.

Ka pipe ipin Kronika Keji 23

Wo Kronika Keji 23:17 ni o tọ