Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 23:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoiada bá rán àwọn ọ̀gágun ọmọ ogun ọgọrun-un pé, “Ẹ fà á síta láàrin àwọn ọmọ ogun, ẹni tí ó bá tẹ̀lé e, ẹ pa á.” Nítorí àwọn alufaa ní kí wọ́n má pa á ninu tẹmpili OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 23

Wo Kronika Keji 23:14 ni o tọ