Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 21:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba wọn fún wọn ní ọpọlọpọ ẹ̀bùn: fadaka, wúrà ati àwọn nǹkan olówó iyebíye, pẹlu àwọn ìlú olódi ní Juda. Ṣugbọn Jehoramu ni ó fi ìjọba lé lọ́wọ́, nítorí pé òun ni àkọ́bí rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 21

Wo Kronika Keji 21:3 ni o tọ