Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 21:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tilẹ̀ kọ́ àwọn pẹpẹ ìrúbọ káàkiri ní agbègbè olókè Juda. Ó fa àwọn ará Jerusalẹmu sinu aiṣododo, ó sì kó àwọn ọmọ Juda ṣìnà.

Ka pipe ipin Kronika Keji 21

Wo Kronika Keji 21:11 ni o tọ