Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 20:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jehoṣafati ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ lọ láti kó ìkógun, wọ́n rí ọpọlọpọ mààlúù, ati ẹrù aṣọ ati nǹkan ọ̀ṣọ́ olówó iyebíye. Wọ́n kó wọn títí ó fi sú wọn. Odidi ọjọ́ mẹta ni wọ́n fi kó ìkógun nítorí pé ó ti pọ̀ jù.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:25 ni o tọ