Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 20:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan wá sọ fún Jehoṣafati pé ogun ńlá kan ń bọ̀ wá jà á láti Edomu ní òdìkejì òkun. Wọ́n sọ pé àwọn ọ̀tá náà ti dé Hasasoni Tamari, (tí a tún ń pè ní Engedi).

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:2 ni o tọ