Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 20:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò ní jagun rárá, ẹ sá dúró ní ààyè yín, kí ẹ sì farabalẹ̀, ẹ óo sì rí bí OLUWA yóo ti gba ẹ̀yin ará Juda ati Jerusalẹmu là. Ẹ má fòyà, ẹ má sì jẹ́ kí ọkàn yín rẹ̀wẹ̀sì, Ẹ lọ kò wọ́n lójú lọ́la, OLUWA yóo wà pẹlu yín.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:17 ni o tọ