Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 20:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ fetí sí mi, gbogbo ẹ̀yin ará Juda ati ti Jerusalẹmu ati ọba Jehoṣafati, OLUWA ní kí ẹ má fòyà, kí ẹ má sì jẹ́ kí ọkàn yín rẹ̀wẹ̀sì nítorí ogun ńlá yìí; nítorí pé kì í ṣe ẹ̀yin ni ẹ ó ja ogun ńlá yìí, Ọlọrun ni.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:15 ni o tọ