Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 20:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun wa, dá wọn lẹ́jọ́. Nítorí pé agbára wa kò tó láti dojú kọ ogunlọ́gọ̀ àwọn ọmọ ogun wọn tí wọn ń kó bọ̀ wá bá wa jà. A kò mọ ohun tí a lè ṣe, ìwọ ni a gbójú sókè tí à ń wò.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:12 ni o tọ