Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún fi kún un pé, “Ìyìn ni fún OLUWA Ọlọrun Israẹli tí ó dá ọ̀run ati ayé, tí ó fún Dafidi ní ọmọ tí ó gbọ́n, tí ó sì ní òye ati ìmọ̀ láti kọ́ tẹmpili fún OLUWA ati láti kọ́ ààfin fún ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 2

Wo Kronika Keji 2:12 ni o tọ