Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 18:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun gbóná ní ọjọ́ náà, Ahabu ọba bá rá pálá dìde dúró, wọ́n fi ọwọ́ mú un ninu kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, ó kọjú sí ogun Siria. Ṣugbọn nígbà tí oòrùn ń wọ̀ lọ, ó kú.

Ka pipe ipin Kronika Keji 18

Wo Kronika Keji 18:34 ni o tọ