Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Asa ọba ní ọ̀kẹ́ mẹẹdogun (300,000) ọmọ ogun ní ilẹ̀ Juda, tí wọ́n di ihamọra pẹlu apata ati ọ̀kọ̀ ati ọ̀kẹ́ mẹrinla (280,000) láti Bẹnjamini tí wọ́n di ihamọra pẹlu apata ati ọrun. Gbogbo wọn ni a ti kọ́ ní ogun jíjà tí wọ́n sì jẹ́ akọni.

Ka pipe ipin Kronika Keji 14

Wo Kronika Keji 14:8 ni o tọ