Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 14:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó gbogbo àwọn pẹpẹ ìrúbọ ati àwọn pẹpẹ tí wọ́n ti ń sun turari ní gbogbo àwọn ìlú Juda jáde. Alaafia sì wà ní àkókò ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 14

Wo Kronika Keji 14:5 ni o tọ