Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó àwọn pẹpẹ àjèjì ati àwọn pẹpẹ ìrúbọ wọn kúrò, ó wó àwọn òpó oriṣa wọn lulẹ̀, ó sì fọ́ ère Aṣera.

Ka pipe ipin Kronika Keji 14

Wo Kronika Keji 14:3 ni o tọ