Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 14:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Asa ati àwọn ogun rẹ̀ lé wọn títí dé Gerari. Ọpọlọpọ àwọn ará Etiopia sì kú tóbẹ́ẹ̀ tí wọn kò lè gbá ara wọn jọ mọ́; wọn sì parun patapata níwájú OLUWA ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀. Àwọn ọmọ ogun Juda sì kó ọpọlọpọ ìkógun.

Ka pipe ipin Kronika Keji 14

Wo Kronika Keji 14:13 ni o tọ