Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 13:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn agbára Abija bẹ̀rẹ̀ sí pọ̀ síi. Iyawo mẹrinla ni ó ní; ó sì bí ọmọkunrin mejilelogun ati ọmọbinrin mẹrindinlogun.

Ka pipe ipin Kronika Keji 13

Wo Kronika Keji 13:21 ni o tọ