Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Mikaya, ọmọ Urieli ará Gibea.Nígbà kan, ogun bẹ́ sílẹ̀ láàrin Abija ati Jeroboamu.

Ka pipe ipin Kronika Keji 13

Wo Kronika Keji 13:2 ni o tọ