Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, wolii Ṣemaaya lọ bá Rehoboamu ati gbogbo àwọn olóyè Juda, tí wọ́n ti péjọ sí Jerusalẹmu lórí ọ̀rọ̀ Ṣiṣaki ọba Ijipti. Ó sọ fún wọn pé, “OLUWA ní ẹ ti kọ òun sílẹ̀, nítorí náà ni òun ṣe fi yín lé Ṣiṣaki lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 12

Wo Kronika Keji 12:5 ni o tọ