Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, ‘Ẹ kò gbọdọ̀ lọ bá àwọn arakunrin yín jà. Kí olukuluku yín pada sí ilé rẹ̀ nítorí èmi ni mo jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yìí ó ṣẹlẹ̀.’ ” Wọ́n gbọ́ràn sí OLUWA lẹ́nu, wọ́n pada, wọn kò sì lọ bá Jeroboamu jagun mọ́.

Ka pipe ipin Kronika Keji 11

Wo Kronika Keji 11:4 ni o tọ