Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 11:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dọ́gbọ́n fi àwọn ọmọ rẹ̀ ṣe olórí káàkiri, ó pín wọn káàkiri jákèjádò ilẹ̀ Juda ati Bẹnjamini ní àwọn ìlú alágbára. Ó fún wọn ní ohun tí wọ́n ṣe aláìní. Ó sì fẹ́ iyawo fún gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 11

Wo Kronika Keji 11:23 ni o tọ