Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Rehoboamu dé Jerusalẹmu, ó kó ọ̀kẹ́ mẹsan-an (180,000) àwọn akọni ọmọ ogun jọ láti inú ẹ̀yà Juda ati Bẹnjamini, láti bá àwọn ọmọ Israẹli jagun, kí ó lè fi ipá gba ìjọba rẹ̀ pada.

Ka pipe ipin Kronika Keji 11

Wo Kronika Keji 11:1 ni o tọ