Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 10:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Rehoboamu bá lọ jíròrò pẹlu àwọn àgbààgbà Israẹli tí wọ́n bá baba rẹ̀ ṣiṣẹ́ nígbà ayé rẹ̀, ó ní, “Ẹ fún mi ní ìmọ̀ràn, irú èsì wo ni ó yẹ kí n fún àwọn eniyan wọnyi?”

Ka pipe ipin Kronika Keji 10

Wo Kronika Keji 10:6 ni o tọ