Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 10:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba rán Hadoramu tí ó jẹ́ olórí àwọn akóniṣiṣẹ́ sí àwọn ọmọ Israẹli, ṣugbọn wọ́n sọ ọ́ lókùúta pa. Rehoboamu ọba bá yára bọ́ sinu kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, ó sá àsálà lọ sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Kronika Keji 10

Wo Kronika Keji 10:18 ni o tọ