Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Fadaka ati wúrà tí ọba kójọ, pọ̀ bíi òkúta ní Jerusalẹmu, igi kedari sì pọ̀ bí igi sikamore tí ó wà ní Ṣefela, ní ẹsẹ̀ òkè Juda.

Ka pipe ipin Kronika Keji 1

Wo Kronika Keji 1:15 ni o tọ