Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 9:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n tọ Joṣua lọ ninu àgọ́ tí ó wà ní Giligali, wọ́n wí fún òun ati àwọn ọmọ Israẹli pé, “Ọ̀nà jíjìn ni a ti wá, nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á dá majẹmu.”

Ka pipe ipin Joṣua 9

Wo Joṣua 9:6 ni o tọ