Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 9:4 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n lo ọgbọ́n, wọ́n tọ́jú oúnjẹ, wọ́n mú àwọn àpò ìdọ̀họ tí wọ́n ti gbó, wọ́n dì wọ́n lé orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn. Wọ́n mú awọ ìpọnmi tí ó ti gbó, tí wọ́n sì ti lẹ̀,

Ka pipe ipin Joṣua 9

Wo Joṣua 9:4 ni o tọ