Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 9:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn láti ọjọ́ náà ni Joṣua ti sọ wọ́n di ẹni tí ó ń ṣẹ́ igi, tí ó sì ń pọn omi fún àwọn eniyan Israẹli, ati fún pẹpẹ OLUWA. Títí di òní, àwọn ni wọ́n ń ṣe iṣẹ́ náà ní ibi tí OLUWA yàn pé kí àwọn ọmọ Israẹli ti máa jọ́sìn.

Ka pipe ipin Joṣua 9

Wo Joṣua 9:27 ni o tọ