Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 8:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà Joṣua ka gbogbo òfin náà sókè ati ibukun tí ó wà ninu rẹ̀, ati ègún, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti kọ ọ́ sinu ìwé òfin.

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:34 ni o tọ