Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 7:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá gbadura, ó ní, “Yéè! OLUWA Ọlọrun! Kí ló dé tí o fi kó àwọn eniyan wọnyi gòkè odò Jọdani láti fà wọ́n lé àwọn ará Amori lọ́wọ́ láti pa wọ́n run? Ìbá tẹ́ wa lọ́rùn kí á wà ní òdìkejì odò Jọdani, kí á sì máa gbé ibẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 7

Wo Joṣua 7:7 ni o tọ