Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 7:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Ai pa tó mẹrindinlogoji (36) ninu wọn, wọ́n sì lé gbogbo wọn kúrò ní ẹnubodè wọn títí dé Ṣebarimu. Wọ́n ń pa àwọn ọmọ Israẹli bí wọ́n ti ń dà gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè náà. Ọkàn àwọn ọmọ Israẹli bá dààmú, àyà wọn sì já.

Ka pipe ipin Joṣua 7

Wo Joṣua 7:5 ni o tọ