Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 7:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kó òkítì òkúta jọ sórí rẹ̀. Òkítì òkúta náà sì wà níbẹ̀ títí di òní olónìí.OLUWA bá yí ibinu rẹ̀ pada. Nítorí náà ni wọ́n ṣe ń pe ibẹ̀ ní àfonífojì Akori.

Ka pipe ipin Joṣua 7

Wo Joṣua 7:26 ni o tọ