Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 7:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó ẹ̀yà Juda wá ní agbo-ilé kọ̀ọ̀kan, wọn sì mú agbo-ilé Sera. Ó kó agbo-ilé Sera wá, wọ́n sì fa àwọn ọkunrin ibẹ̀ kalẹ̀ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan, wọ́n bá mú Sabidi.

Ka pipe ipin Joṣua 7

Wo Joṣua 7:17 ni o tọ