Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Israẹli ti ṣẹ̀, wọ́n ti rú òfin mi. Wọ́n ti mú ninu àwọn ohun tí a yà sọ́tọ̀, wọ́n ti jalè, wọ́n ti purọ́, wọn sì ti fi ohun tí wọ́n jí pamọ́ sábẹ́ àwọn ohun ìní wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 7

Wo Joṣua 7:11 ni o tọ