Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 7:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli dẹ́ṣẹ̀ sí OLUWA nítorí pé ẹnìkan mú ninu àwọn ohun ìyàsọ́tọ̀. Akani ọmọ Karimi, ọmọ Sabidi, ọmọ Sera, láti inú ẹ̀yà Juda, mú ninu àwọn ohun ìyàsọ́tọ̀, inú sì bí OLUWA gidigidi sí àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Joṣua 7

Wo Joṣua 7:1 ni o tọ