Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 6:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Joṣua dá Rahabu aṣẹ́wó sí, ati ilé baba rẹ̀, ati gbogbo àwọn eniyan rẹ̀, wọ́n sì ń gbé ààrin àwọn ọmọ Israẹli títí di òní yìí; nítorí pé, Rahabu ni ó gbé àwọn amí tí Joṣua rán lọ wo ìlú Jẹriko pamọ́.

Ka pipe ipin Joṣua 6

Wo Joṣua 6:25 ni o tọ