Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ẹẹkeje, lẹ́yìn tí àwọn alufaa fọn fèrè wọn, Joṣua pàṣẹ fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹ hó yèè! Nítorí OLUWA ti fi ìlú yìí le yín lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Joṣua 6

Wo Joṣua 6:16 ni o tọ