Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Balogun àwọn ọmọ ogun OLUWA dá Joṣua lóhùn pé, “Bọ́ bàtà ẹsẹ̀ rẹ, nítorí ibi tí o dúró sí yìí, ilẹ̀ mímọ́ ni.” Joṣua sì bọ́ bàtà ẹsẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 5

Wo Joṣua 5:15 ni o tọ