Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

ó wí fún wọn pé, “Ẹ kọjá lọ níwájú Àpótí Majẹmu OLUWA Ọlọrun yín, sí ààrin odò Jọdani, kí ẹnìkọ̀ọ̀kan sì gbé òkúta kọ̀ọ̀kan lé èjìká rẹ̀. Kí iye òkúta tí ẹ óo gbé jẹ́ iye ẹ̀yà tí ó wà ninu àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Joṣua 4

Wo Joṣua 4:5 ni o tọ