Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 4:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí OLUWA Ọlọrun yín mú kí odò Jọdani gbẹ títí ẹ fi rékọjá sí òdìkejì rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ó ti mú kí Òkun Pupa gbẹ, títí tí ẹ fi là á kọjá.

Ka pipe ipin Joṣua 4

Wo Joṣua 4:23 ni o tọ