Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ fún Joṣua pé, “Lónìí ni n óo bẹ̀rẹ̀ sí gbé ọ ga lójú gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, kí wọ́n lè mọ̀ pé bí mo ti wà pẹlu Mose, bẹ́ẹ̀ ni n óo wà pẹlu rẹ.

Ka pipe ipin Joṣua 3

Wo Joṣua 3:7 ni o tọ