Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹ ya ara yín sí mímọ́ nítorí pé OLUWA yóo ṣe iṣẹ́ ìyanu láàrin yín ní ọ̀la.”

Ka pipe ipin Joṣua 3

Wo Joṣua 3:5 ni o tọ