Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹsẹ̀ àwọn alufaa tí wọ́n gbé Àpótí Majẹmu OLUWA gbogbo ayé bá kan odò Jọdani, odò náà yóo dúró; kò ní ṣàn mọ́, gbogbo omi tí ń ṣàn bọ̀ láti òkè yóo sì wọ́jọ pọ̀ bí òkítì ńlá.”

Ka pipe ipin Joṣua 3

Wo Joṣua 3:13 ni o tọ