Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 3:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni ẹ óo fi mọ̀ pé Ọlọrun alààyè wà láàrin yín, kò sì ní kùnà láti lé àwọn ará Kenaani, àwọn ará Hiti, àwọn ará Hifi, àwọn ará Perisi, àwọn ará Girigaṣi, àwọn ará Amori, ati àwọn ará Jebusi, jáde fun yín.

Ka pipe ipin Joṣua 3

Wo Joṣua 3:10 ni o tọ