Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 24:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo kó àwọn baba yín jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti. Nígbà tí ẹ dé etí òkun, àwọn ará Ijipti kó kẹ̀kẹ́ ogun ati àwọn ẹlẹ́ṣin, wọ́n sì lé àwọn baba yín títí dé etí Òkun Pupa.

Ka pipe ipin Joṣua 24

Wo Joṣua 24:6 ni o tọ