Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 24:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli sin OLUWA ní gbogbo àkókò tí Joṣua fi wà láàyè, ati ní àkókò àwọn àgbààgbà tí wọ́n ṣẹ́kù lẹ́yìn Joṣua, tí wọ́n mọ gbogbo ohun tí OLUWA ṣe fún Israẹli.

Ka pipe ipin Joṣua 24

Wo Joṣua 24:31 ni o tọ