Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 24:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Joṣua dá àwọn eniyan náà lóhùn pé, “Ẹ kò lè sin OLUWA, nítorí pé Ọlọrun mímọ́ ni, Ọlọrun owú sì ni pẹlu, kò sì ní dárí àwọn àìṣedéédé ati ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín.

Ka pipe ipin Joṣua 24

Wo Joṣua 24:19 ni o tọ