Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 23:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun yín yóo máa tì wọ́n sẹ́yìn fun yín, yóo máa lé wọn kúrò níwájú yín, ẹ óo sì gba ilẹ̀ wọn bí OLUWA Ọlọrun yín ti ṣèlérí fun yín.

Ka pipe ipin Joṣua 23

Wo Joṣua 23:5 ni o tọ